
- Obo Bobo
Views 43
Downloads 0-
File size 92KB - Author/Uploader: jeje miracle odunitan
*IPARA AWURE TODAJU ” ao gun iye agbe meta, iye aluko meta, ikode meta, ao gun won papo mo osun pupa die, ao wa teni ejiogbe, ao pe ohun re si, lehin na ao da sinu adin agbon. OHUNRE :- olayemi awo won lode egba, oladewa awo won lode ijesha, onhan onhin ohun ewa ni won jonwo ilu, agbe kiti ni maro, aluko kite ni mosun, odidere kiti ni mako, oro emi lagbaja omo lagbaja Di osun, odi adin momu kun ori, momu kun gbogbo ara, ki oro mi jasi eyee larin gbogbo eniyan nitoripe agbe kiti ni Moro kinmasete larin egbe o, aluko kiti ni mosun, odidere kiti ni mako kinmase te lowo oso, aje, elebologun, emere, asebi aiye, lowo okunrin ati obinrin. Ao wa mafi para wa ti abatinjade. Odaju
*OSE AWENU TODAJU ” egbo tude ati ewe re, isawuru meje toni omo ninu, eso oju olongbo topo die, ata ijosi die, epo obo die, igi nla die, ao gun won kunna dada mo ose, ao ko sinu igba olomori kan, ao DE pa, ao ge pamo fun ojo meje, ao mafi we lehin ojo keje pelu fifi epo pupa para Kato we.
“ASEJE ASINA OWO TODAJU” aseje yi daju tara, gbogbo eni keni toba rise ki olohun fi alubarka si. Iye agbe kan, iye aluko kan, ori eye owiwi meta, ao gun kunna dada pelu ata ijosi iyekiye tabi iyere, ao wa fi se oju malu 32 je lepo niyo, ao so sori osuka aso funfun, ao se adua si, ao wa je, any time ni jije re.
*ISORA TOBURU TI A MAA NFI NRAN OKU SI AWON OTA Ao han Suratul Masad Meje sinu paper funfun kan, Ti aba de ori Elekeje, Mim to pari re ao bu Mim yen ti yio fe daadaa, ao da aniyan wipe gbogbo eniti nba nperi Emi Lagbaja nibi Okunrin ni o, obinrin ni o ti won nba nsa Ogun buruku simi ki gbogbo won ki won maa ku kotodi ojo keje, lehin naa ao lo wa Iyepe oju titi ti motor ngba daadaa gegebi Express way, ati iyepe sare okunrin ati obinrin, ao fi se gari tira naa, ao di ni owu pupa, ao lo ri mo ori sare oku ti won ti sin tipe tipe. tobadi Ojo keji ti ase ise yii ao bere sinu saa Suratul Masad 1000 fun 7 days. Ti abalagbaara ale fi awe gbigba se adua naa fun 7 days, Laye awon Ota yin baa baje. Gbogbo ala yin ti e baa nla lehin adua yii, Ala isegun ni.
OGUN TI ORUKA BURUKU KONI RAN WAA TI WON BAA KAA OUNDE TABI ORUKA
BURUKU LU WAA, ORUKA NAA YIOLO DAHUN PADA LARA OTA NAA ako alangba kan, odindin ataare kan ao jo ao lo kuna, ao di si ibi kan, ao tun jo abo alangba ati ataare kan papo, ao lo kuna ebu mejeji ko gbodo kan ara won oo, ao sin gbere si oke ikun waa ao fi ebu ako paa ibe, ao sin gbere round isale ikun waa ao fi ebu abo paa oju gbere naa, opari, opo enia le sin. bi won baa fi ogun buruku naa waa ha?????????? aiye enia naa baje
ASEJE BIBO ASIRIBIBO Ao ge igbin apinnu meji si 25-25, Ewe Tanaposo 25, ododo tanaposo 25, iyere 25, N1000 tuntun tabi iru owo ti o ba tobiju ni ilu ti aba waa ao ko oruko wa ati oruko iyawa wi oju mejeji owo naa, ao lo peli iyere 25, ao lo gbogbo re papo, omi hantu Suratul Wakiah kan lao fi se paseje pelu epo ati iyo, Olohun yio biya Bukata eni ti o ba je aseje yii ni osu naa, odaju samu
ADURA TIAFINKOJU EYIKEYI ISORO YALA OGUN OTA, OGUN IDILE, ABI EYIKEYI OGUN AIFOJURI TONBA OMO ENIYAN FINRA TIKOJEKI ONI ILOSIWAJU NINU IRIN AJO AYEERE TI OBATI JA EWE TOSITI WA EGBO TOJEWIPE OJU KAN NAN LONJASI, IWO OMO IYAMI DAKUN NI IGBAGBO KOSIGBIYANJU ADURA YII WOO HNMM NINU EPE NINU ADURA WAASEKAN Aowa aso pupa, aoran ni deede sokoto ewu, ati fila, tobawadi deede agogo mejila abo oru (12:30a Aose Aluwala Aoyan Nafilah Rakah 2, Fathia 99 Lori iduro kookan, aonikaa surah kankan leyin re, aowa salamo, sugbon origun mereerin laoyan nafilah meji meji yen sii, aomaasalamo ni origun kookan, leyin salamo aodojuko kiblah (gabasi) aomu tesbah aose ISTIGFAAR……..1000 ASALATU ALA NABIYYI……..1000 HASBUNALAH WANIMOL WAKEEL……..4 050 Aodide aolosun, aosebee fun ojo meje, leyin ti ojo meje bape……….Aodin akara elepo pupa, abi kapa adire akuko totobi daada, aofise sahara, hnmmm Ti oro eeyan kobatiidebi wipe kofeeni ojutu Mon kodakun komase iseyii ooo, bi iseyii se rora kere mon, wonmanfi pa ota tobako tikofeejawo ninu oro aye yan nii ooo,,, aiye oni muwa o, gbogbo Lao segun awon ota wa ola anobi Mohammad,,, ameen. Omo odo agba worldwide
AGBO AISAN KI AISQN NINU ARA Ewe Pear ao ja kopo die, ao se ni agbo fun mimun gbogbo aisan ara lo nsise fun odaju
*AWURE OWO* ewe Tomatoes ojo topo die,igbo ti won mu Ku,ao lo won papo mo ewe onitikuti yen,iyere die,ao fi se igbin toba pinu kan je,lepo niyo,ao wa mu oti star meji le Lori. Posted by Olatiboye Mutiu at 10:19 AM No comments: Email This
BlogThis! Share to Twitter Share to Facebook Share to Pinterest
*OGUN AWURE* A o wa ewe agogo igun tutu , eru Alamo, a o gun mo ose dudu, a o fi iyeru osun te ifa ika meji , a o pe gbolohun si , a o dasi ose yi, a o po dada, a o gbesi ilenle igun ile, a o pe gbolohun si , a o so fun pe ose na pe Iwo ose yi , aini owo lowo ni mofi ko e si ilele nle, ti oba mu owo wa fun mi , inu igba golu ( gold) ati fadaka ni unko o si , a o ma fiwe laro. gbolohun re : moyo nje moyo, moko nje moko, lodifafun orunmila, tinfi efufulele yo lojojumo aiye, oni olowo ti mbe lapa okun ki owa jemi, oni olowo ti nbe lapa osa kowa jemi, ika meji Iwo loka ire gbogbo aiye , ki o loka olowo wa , ki owa funmi lowo, ki olo ka olola wa, ki o wa fun mi lowo. ……… Posted by Olatiboye Mutiu at 10:31 PM No comments: Email This BlogThis! Share to Twitter Share to Facebook Share to Pinterest IKEDE PATAKI Eyini lati so fun gbogbo awa ololufe blog yii wipe, ati nse ipade ojukoroju ni state kokan, ilu kokan fun ilosiwaju ewe ati egbo, ati lati ma fi Awon unkan ran arawa lowo, ori what’s up lati koko fe bere eto yii, lehin naa ao maa se ipade ilo siwaju egbe yii ni fave to face. Eleyi ni awon Zone ti o ti wa nile bayi, ki e add what’s up link naa lati join IKORODU ZONE https://chat.whatsapp.com/164IhdY3vj98nDDN9YBW10 IJEBU ZONE https://chat.whatsapp.com/D8iIDyAQnIs9SeJfacLCYG ABEOKUTA ZONE https://chat.whatsapp.com/EvxNeiYpRJg6PGkoeZcHJP SANGO OTA ZONE https://chat.whatsapp.com/9kg4sxIVTEx72kGnd4UDvj IBADAN ZONE https://chat.whatsapp.com/KLKhoGcd4W4JBevDH1sK8h YABA AND ISLAND ZONE
*OGUN AFORIJIN : a o wa ewe orijin tutu die , iru die , iyere die , a o lo po , a o fa sinu isasun kekere kan , a o fi epo si ati iyo , a o fi se eja aro je , ti Oba jina , a o so sori osuka , a o so wipe , iwo lagbaja omo lagbaja , gbogbo ounti moba se fun e , ki ofi orijin mi. BlogThis!
ISORA AGBELEPOTA, ASINA APA EGUN ATI EPE RUN Ao han suratul Masad 71, Ao gun ewe Akonimora tutu mo ose dudu pelu epo obo die, ao fi omi hantu yen fo, ao fi ako okuta kan si inu igba olomori kan, ao waa fo eyin ororo kan mo okuta inu igba yen, ti eyin yen bati fo, ao ko ose yen le lori, ao fi obe tuntun kekere kan tabi obe esu gun ose yii legbe, ao fi omori re de pada,
ao lo gbe pamo fun 41 days, lehin 41 day lao to lo si wo, bi enia ba de idi ose yii ti 41 days koti to ti o waa losi igba yii wo, eni naa kotun rina mo laye, oju eni naa yio fo ni, ao maa fi obe yen bu si ori kein kein fun wiwe lalale, Alasasi yio ku, onaa yio si si fun waa, ti awon ota baa fe maa saa siwa,, won yio ma ku ni. Odaju
“OSE ATUDE EBE AWON AGBA TI ONA BADI TAN YAN YAN”…………Hmmmmmm Omo iya mi jowo mase fi oju di asiri yi, mawo ti ki kere tio kere, iwo dan wo kio gba wipe Asiri siwa toun je, atiwipe wibe jebe ti olorun nise………..Ao wa egbo Tude, ao gun pelu odidi atare meta, ti yio kuna daada, ao wa po papo mo ose dudu, ao wa opolo aye nla meji, ao ko tele ike funfun, ao wako ose yile opolo yan lori, ao depa ao gbe pamo fun ojo meje, after seven days, ao mafi we lale pelu omi tolo wooro(EWE NJE BEN KUNFAYAKUN OLORUN LAGBOJU LE)
*AWURE TODAJU.. .ao ra monlu Ekirikan ao gbodo naa iyekiye ti won ba pe owo re ni agbódò ra ao gesi mesan ao se ni lepo niyo pelu ewe ewuro die ‘ewe aje pupa’ ewe iyalode ao gun po afi se obe je ti aba ti fe maa je óbe naa ao mo se adura gbogbo ohun ti aba fe si.
*OSHOLE KEKERE.. . Oga gbagbe kan, ewe ola die, agbado eyo mesan, Atare aja kan, ao jo papo, ao fi Milk olope lo lekan, ale ni alo ooo.
FUN ALAYE LEKUNRERE LORI IRAWO RE Fun Alaye to peye lori irawo ti o mun waye Ise ti o ye ki o maa se Ojo ti o yeki o maa se Adua Ojo ti o ye ki o maa lo ogun Iru aso toba eleda re mun Iru ounje to ye ki o sora fun Epe si ori numbers mi O7037422552 or 08029484696 Nigeria N3000 Others $14.29 USD Pay to thia account Account Name Olatiboye Mutiu Taiwo Account Number 0117874829 Bank Name Gtb Call me after the transaction
AKIYESI PATAKI Opo igba ni awa omo eda nsun gbagbe, opo ninu eda ni koni akiyesi, opo lo ti lo se ayewo si oro aiye re ti obaa de ibi kan bi won ko ba so wipe awon agba lo nda lamun won asope iya re ni o waa ni idi oro re, igbamiran won a ni egun idile, ohun ti awa omo eda nfi owo ara waa faa gan ngba miran gan ju ki awon apapo agba ma da enia lamun lo. Ojo kokan ninu osu loni ohun ti o nba enikokan wa rin, Irawo ati Ojo ibi maa nda opo eda lamun, ,, opo igba loti lo ogun dudu sibe sibe pabo lo nja si, boya eleda re ko lo ni ilana unkan be sibe sibe o ko agidi bori oni dandan iwo naa fe se ogun osole! 1. Irawo Omi, Ewe ki je lara iwo omi, ogun asasi ota ki si saba ran won, Je enikan ti yio maa saba lo Hantu, tabi ki o maa se Adua si omi, Ebu lilo ki je lara won, bi won ba fi Millions se Ebu fun won ko le sise, Ose si nma nsise die die lara ju Ebu lo 2. Irawo Ina. Ha! Irawo yii gbodo je enikan ti o nso ara re kuro lori wiwe ose ni gbogbo igba, Bi ose wiwe ba po lapoju o da gegebi eni npa ogo ati imole ara re ni, Ebu a maa sise daadaa lara won ju ose lo 3. Irawo Afefe… Awon irawo yi gbodo je enia ti ntera mo adua sise lopo lopo, bi won se ni agbara
to be naa ni won yaa ole (lazy) to, ogun asi maa tete je lara won, besi ni asasi ntete maa nmun won, won gbodo munra gidi gidi, won ki fe ki won se aseyege eko, enia nla ni won. 4. Irawo Iyepe, Awon irawo yii maa nje oni suru, won ki tete binu, won gba iwosi sugbon bi won ba binu tan ibinu won ko dara raa, won ki si fe gbo imoran eda miran yato si ti won, inakuna asi maa ba won ja pupo, bi iru irawo yii baa tete munra si isori lati ibere pepe aiye won, won ama bori Awon isoro bi ki owo maa daa lowo won. FUN EKUNRERE ALAYE LORI IRAWO RE, IRU ISE TI O LE SE, IRU AWON IGBIYANJU TI O LE MAA SE GEGEBI OGUN, IRU ASO TI O YE KI O MAA WO, IRU AKOKO ATI OJO TI O YE KI O MAA SE ADUA TABI OGUN ETC E PE SI ORI NUMBERS YII FUN EKUN RERE ALAYE PELU OWO EGBERUN META PERE N3000 Naira N3000 Dollars $14.20 USD 07037422552 or 08029484696
EPE TO DAJU Ao waa Ose Kekere kan, ao fi Ato idi waa po po daadaa, ao ju eyo atare kan si inu iwo etu, ao ko ose yen sinu iho etu yen, ao fi kan enu sepe ti aba fe se. Ti aba fe danwo ao lo si idi igi kan ao fi epe yen kan enu lemeta ao so wipe Ki iwo igi yi ku ni wakati bai bai, ti aba pada de idi igi yii yio ti ro ewe. Odaju Lati owo Khosim Hayemu ilu igboho
ASEJE OLA TODAJU Igbin meta, Eja Aro tutu meta, Eran malu ao gesi meta, N1000 meta ti letter T baa bere, ao han Izaja si oju ati eyin owo metetaa, ao jeki o gbe daadaa, ao wa gesi meta meta ao lo kuna dada pelu ewe Aje, ata ijosi, ao lo kuna, ao fi se won je laseje, ago kan abo oru lao je pelu adua ola nla, odaju
ISORI TOLAGBARA GAN AN . Eran aja, ati eran elede, odidi atare kan totobi dada, opolopo ewe oriri, ao jo papo, tia ba tan ao fi te owo ifa odu merindinlogun, fi foko mu. OFORE : – Akii fi asisan pa aja, akii fi igede pa elede, ifakifa kile odu merindinlogun lori ate, ohun ti oba tobi laiye oriri ni nri, babalawo lo nperi mi nibi, onisegun lonpe ori mi ni ibi, alufa lonpe ori mi ni ibi, oso ni, aje ni, okunrin ni, obinrin ni, omode ni, agbalagba ni, enikeni tio ba npe ri mi ni ibi oriri bami riwon mole oriri, ti aba njo ogun yi lowo ako gbodo roro ti ama fi jo tan o.
HOW TO USE WHITE CANDLE FOR SPECIAL PRAYER Get a white get 7 white candle, inscribed this on each candle 787, place the candle in front of you and light all the candle, keep saying ١٢٠٠٠ بسم هللا الرحمن الرحيمwhen u are done pack all the remaining and bury them with your left leg. InshaAllah your prayer will surely be answered.. Please keep praying for our Muslim Brother and Sisters in Burma
TURARI ADUA GBIGBA Turari yii a maa nfi ngba Adua fun awon Enia ti o waa ni ona jinjin, papa julo Eda ti o baa je
ategun ninu won bi enia baa lo Turari yii fun won lati ba won fi se adua, adua naa ntete maa ngba. Ao waa Ewe gbegbe tutu 201, lori ewe kokan ao maa han Inamo Amuruhu isa aradan shean anyakululahu kunfayakun ao maa han meje meje lori ewe kokan titi yio fi pe 201, ao waa ewe Ogbo 201, ao han Salamu kaola mi nrobi roheem meje meje si ori ewe kokan, ao waa saa kofi gbe daadaa, ao gun pelu awon eronja won yii 1. Iye agbe 7 2. Iye Aluko 7 3. Iye Odidere 7 4. Iye Lekeleke 7 5. Turari Lubansakara 6. Kajiji dudu ati pupa 7. Imi Ojo die pelu etu ibon gidi ao gun papo daadaa, ao maa fin fun ojo meje pelu gbigba Adua fun eni naa ao si maa daruko eni naa ati ilu ti o waa pelu ohun ti o nfe, larin Ojo keje Walahi, eni naa yio pe yin wipe Adua naa ti gba. Ti Adua naa baa gba tan ao pa Odindin Agbo kan fun sara adua naa. Ti aba ko ti ao baa pa Agbo naa, Eniti o se Adua naa yio maa ri Idiwo kokan. Ale koko ti gba owo eran Agbo ki ato baa bere adua naa. Akiyesi Ti abaa nfin turari yii lowo ao maa saa suratul Yasin meje meje lojojumo fun ojo meje, ko gbodo koja ojo meje kosi gbodo maa pe ojo meje
*IPESE AWON AGBALAGBA Ao wa awo ipese funfun kan, ao waa eko Elewe kan, ao gbe eko yii sinu awo naa ao ki eyin adie ororo kan si larin, ao won iyo die si, ao se opolopo adua si, wipe ki Ogun maa je lara mi ejeki gbogbo ogun ma je lara mi, ejeki gbogbo ogun ti mo ba se fun awon eni maa je lara won, ema se ba ogun ara mi je mo, Adua to ba wuwa ao maa se lehin naa ao gbe lo si ibi ti won ti maa ngba ipese Ao han ni igba eyokan pere si oju walah, ao waa fi omi lasan fo, ao maa da omi yii sinu omi iwe waa ni alale ao ma fi san ara ao maa se be fun ojo meje, ale maa fi we gbogbo awon omo ati iyawo waa naa. ISORA KURO LOWO AWON EMI OKUNKUN NI
OSE OSHOLE OWO TODAJU Ori eyele 1 Ori Eye owiwi 1 Ori eye osin 1 Ori agbe 1 Ori aluko 1 Ori igun 1 Ori akuko adie 1 Aoko a won ori mejeeje yii sinu igba olomori kan, aowa ewe etiponola aoso okunmon, aomaawobowa sinu ile tangbe, aowaja 201, laraare, aogun ewe yen lasan pelu ose dudu……….aowako oseyen sori awon ori mejeeje towani ninu igba, aogbepamo fun 7 days, leyin ojo meje, aomaafiwe laraaro odaju
ADUA ITUSILE TODAJU Ao raa candle pupa 16, pelu dudu 16, amaa tan ina candle yii circle ara waa ti aba tan black candle, ao tan red tele be lao se maa tan titi yio fi circle ara waa, ao joko si ni arin, ao waa maa saa Suratul Yasin, gbogbo igbati abaa ti nsa Ayah Yasin kan ao maa saa Suratul Fil 71 times be lao se saa titi ao fi pari YASIN ti gbogbo candle yen ba ti jo tan ao ko gbogbo erunrun to ba ku ao lo bo bole, Gbogbo Enti o bqa ti sa Ogun buruku si wa ri laye, ti won baa si wa lori epe, ao ma gbo ofo awon ota lokunrin ati lobinrin, ayqfi ti won ko baa se aburu siwq ri loku. Ti aba ti pari eto yii ao gbe koto to jin daada ao du akuko pupa kan si inu koto naa ao waa da erunrun candle yen si inu koto naa, odaju
OSE OSHOLE OWO TODAJU Iye agbe 7 Iye aluko 7 Ikoode 7 Ori Agbe 1 Ori aluko 1 Ori odidere 1 Ewe aje Tutu tabi gbigbe Ewe birana tutu tabi gbigbe Ewe aanu tutu tabi gbigbe Aogun gbogbo re papo aowapomo ose dudu……….Aowa ori aguntan tiwonpa loojo Gbogbo owo paper tanan pata N5, N10, N20, N50, N100, N200, N500, N1000 Aoko awon owo yen sinu awo funfun olomori kan…….aogbe ori aguntan si……aoko ose yen siii………aowagbe ose yen sinu apo asunwon funfun aogbeko soke………..idiire kogbodo kanlemon. Aomaabuwe laraaro
TURARI AWORO TODAJU Ao waa Ori Owawa toni irun kan, Ewe awerepepe gbigbe, Eresile Ewe Lapa lapa funfun die, Ewe ajeobale gbigbe, Ewe Abifa gburu gburu, Kaji dudu ati Pupa, Turari Jawal, Igbe Malu gbigbe, egungun ori esin die, ao gun papo ao fi orisi Lofinda 16 po papo, ao ko sinu awo funfun, ibe lao ti ma bu fin ni Araro. Odaju
OSOLE TO SISE BI IDAN…. .Alangba adaripon kan,,Epo obo die,,,imi Ojo die,,atare pelu ikoko tuntun kekere kan ao du eje alangba yi sori isasun yi ao wa GBE alanga ti adu yi le epo obo ye ati imi ojo Lori ao Jo papo mo atare ao wa fi po ose ninu isasun naa ao fi abere oporo kan gun ose yen larin ,,ninu isasun yen naa ni ati malo Ogun yen kiato po lose, ….NB…lojo ti aba koko we oseyi ti aba WO motor conductor koni gbowo lowo wa omatun bere pe Elo ni change ti amagba ni .kia gbo owo naa lowore tori ise na ti bere
: OSE ATUDE. Ewe tude, egbo tude, fitila oloju kan, opolo oye kan. Sisere:-Ao lo ewe tude ati egbo re lotooto ao wa kpo mo ose ao gbe opolo oye yi tele fitila oloju kan yen ao wa ko ose yi le Lori ao fi le fun ojo meta, leyin ojo meta odi wiwe lale. Atakpawi. : OSE TUDE. ESO ABEERE MESAN 9, ERU ALAMO 9, OSE. Ao gun eso abeere loto ati eru alamo loto ao wa kpo lo se odi wiwe lale. Atakpawi…
AGBELEKPOTA EWO EYO EYO KAN , Ao lo ko kunaa daada ao fi singbere kan si Arin ori wa ao lo da iyoku si oju ona ti motor ban gba daada. Hmmmm small but mighty.
Atakpaw +234 907 950 7375: ASEJE AWORO OWO ,EDO MALU AO GE SI 16., IYERE 16, EPO IJEBO, DIE., EPO, IYO. ao lo iyere ati epo ijebo ao fi se Edo malu yi ti agesi ona 16 pelu epo ati iyo. To ba wa jina ao so kale si ori osuka ao wa fi iyere osun te ifa ejiogbe ao wa kpe password re si. Password: ifa ni sanwo3X Ogun ni pase3X Orisa nla ose ore magbo nin da aso alaran bara bora, bi omode ba je owo ifa ni San, bi agbalagba ba je gbese jebo ni bo ki asiri emi l omo l bere sini bo lowo okunrin obinrin lomode lagbalagba ao wa da sinu obe na ao ko je. Hmmmm🙇🙇🙇mmmmm Iba eyin Agba oooooo
+234 907 950 7375: OSO FUNFUN TOJE TI YAHOO ATI ORUKA RE. igbin apinu mejo 8, Odidi ijapa oko nla to tobi kan 1, Odidi atare meta 3. Ao jo kpo ao lo kunna daada ao tin walo AJE OLOKUN merin 4 kunna loto ao wa dapo mo ebu tia Jo yi, ao wa ro sinu sere kan ao pa eyele funfun kan sidi seere yi, ao tun pa eje ako pepeye to tobi daada si ara seere yi ao watu iye re gunju ni apa pepeye ati eyele yen totun ati osi mejeji, ao waso po, aofi di enu seere yii, ao tu iye eyele ati pepeye papo ao wa le mo ara sere naa ao wape ofo re ao mafi ekuru funfun je ni ojo Thursday, but ki ato jo iseyi ao ti koko fi oruka toba wunwa sinu igbin kan ninu awon igbin yen, ti yoo wanu re tan, leyin taba wajo tan ao yio oruka naa kuro, ao fi sinu enu oga oye kan ti yio wonu re daada, ao wa lo ri oga yi si idi agbo ogede fun ojo meje gbako, leyin ojo meje naa ao ma fisi owo chart pelu client wa. OFORE:-igbin ki kole koma ku Aje olokun mope ooooo. Ijapa ki kole tie koma yori re. Aje olokun nimo pe ooooo. Lodidi lodidi ni olugbo nfi igbin tore fun ero ona, Lodidi lapolapo niki omo araye maagbe owo temi wa funmi, ijapa ki kole tie koma yori re, Aje olokun mope oooo, ojulumo ki jeki ahun sun igbe, Lodidi lapolapo legberu legberun, aimoye ni ki omo araye ma gbe owo temi wa funmi.. Walahi won bi client reda too feel san owo fun oooo. Note:- ATUDE to confirm ni ki akoko we oooooo. EGBE AWON AGBA. IPESE TOBA DAAA. Ki ato wa da wo le ise yi…. +225 41 21 33 75: Eyonu kan re. a o wa ewe iyalode fun fun ati pupa , ewe akoko , ewe ajobale , a o gbo sinu Ike kan , a o wa gbe sori ibikan ni idaji ti o bati di ale , a o wa Fi iyo die si , ao wa bu omi ti o bale to wa wesi, a o wa Fi we la Lee . Odaju mo ti lo confirm ni oo..
234 806 357 5803: EBE AGBA orogbo 3, Eyin ibile 3, Eko elewe 3, Odidi atare 1, Ao bo ewe ara eko yen, Ao wa jopo, Leyin ti aba jo tan, Ao mafi fo eko mu Ofore ti aba je eko nse ni aman ndariji ewe ni Gbogbo Ese ti emi lagbaja ba se lokunrin, lobirin lomode lagbalagba edarijimi Orogbo loni ki gbo sinu owo, ola aiku bale oro Nire Nire Bai la soro atare Nire Nire Niki won ma soro mi Enu bayii ni adiye fin ntu eyin re se Lori aba Enu Enu bayii Niki won fi ma
+234 907 950 7375: ASINA AWON AGBA. Ewe ajeobale, ewe mafowo kan omo mi, ewe danguro pelebe, eja ojiji oye ao gun gbogbo eronja yi kpa kpo ao kpo mose ao ko sinu ike rubber funfun kan odi wiwe. Atakpawi…
234 907 950 7375: ASINA Igbin Apinu nla kan, epo obo die, ewe ola, agbon ose. Sise re. Ao gun gbogbo re kpa kpo ko kuna daada ao wa kpo lose ao fi omi agbon kpo daaada lai fi omi si rara ao ko sinu ike funfun kan odi wiwe. Atakpawi… [20/09, 10:16 pm] +234 907 950 7375: ASEJE ASINA. Eye onbe meta. Ewe aluki Ata ijosi 16 Eja aro Ao lo eye onbe yi pelu ewe aluki ati ata ijosi ko kuna daada ao wa ge eja yi Lona meta ti KO ni getan, ao wa fi kini ti alo yi se lepo niyo. Ale ni jije re. Meji meta logun Atakpawi…
229 97 71 96 66: IMULE OLUGBERIGI RE TODAJU eye igun odidi kan Eye owiwi odidi kan Olongbo odidi kan Igbin odidi kan
Ewe agunmona tutu Ewe ajeobale tutu Atare odidi kan SISERE aoko gbogbo kiniyi sinu ape ijogun ki atobere jijore aopa adire akuko kan ao ro eje re yipo aro aotu igo epo pupa kan si oju aro yen ki ato ko igi sinu re ao gbe ogun yen kana ao majo ao mako inare pelu ataijosi ao mabusi diedie ti yio fi jo tan ao bu omi toma sinu igbakan obi abata oloju mefa lona meta ao yaa ni awe kokan sinu omi yi ao se owo were lati #20 topo kale ao kosinu omi yen bakaanna ao bu epo pupa die lee lori awan ti won banbawa nibe ao mafun won obi ati owo awana yio maje pelu ao tun se adire yi kale ti won yio maje ti ogun yi bajotan aolo kunna dada ao te ifa ejiogbe si aope ofore si ao rosinu sere tobalegba ao tun pa akuko adire kan sini ara sere yen aro eje sini ara aotu iye igbaya re ati ti abiyare otun osi naa si aolemon sere ao gbesinu apo aso funfun ao gbeko origun inu ile idire kogbodo tun kanle mon ao malo pelu eko tuntun ni ati ale OFORE Olugberigi olori lonse awo won lode isalu aye*3 Ejeogunre lonsawo won lode otunmoba*3 Okanlawon lonse awo won aratonade akoko*3ohun lodifafun jeki alaye ose aye ohun lodifafun jeki onigba ologba ohun lodifafun jeki elewe ose ewe ohun lodifafun orunmila ni ojo ti baba nloba awan eleye mule nipako oni eyin eleye niboni elo wonni awon lo ile aye ni oni ti eba de ile aye kinni efelomase nibe wonni awon yio lomabati omo enije awon yio silomatun titi omo eniyan se orunmila ni awon omo titi oun nko wonni orunmila yiose imule nitori awon omo tie orunmila ni kinni nkan imule naa wonni ki olowa eye igunugun kan eye owiwi kan odidi olongbo kan odidi igbin kan ewe agunmona ewe ajeofole orunmila wagbogbo re won ni jo orunmila ni esemi ki aye mi oroju ki esemi ki ayemi odara ki esemi ki ona owo nlanla osifunmi nitoripe motidi imule ataata awon aje loni ibeni ifa tise enu tooro ti orin wabosi lenu onpe Oso ilee ejowo miii*3 Aje ilee ejowo moi*3 Bi igunugun baa jebo ajowo igba oooo
+229 97 71 96 66: IMULE AARE AGBAYE (OSO IMULE NLA) A BE ENIKENI TI OJO ORI RE KO BA TO OGOJI ODUN KO MASE DAN OGUN YII WO RARA (40 YEARS) Eye Igun nla ooye kan, ao Jo pelu ataare nla kan nilu kan lojo aiku ao Di ao fi pamo soto Eye kan-nakan-na ooye kan, ao lo jo pelu ataare kan ni ilu Miran yatosi ilu tatijo takoko lojo aiku miran .ao di ao fi pamo soto Olongbo dudu ti koni awo miran lara tiba si ri daju wipe olongbo dudu ni eyo kan, ao Jo bakanna pelu ataare kan ilu miran lojo aiku miran ao di ao tun fi pamo soto. Oga ooye kan, ao Jo pelu ataare odidi kan nilu miran lojo aiku Ao wa ro gbogbo re papo
sinu akeregbe, ao pa eran ewure kan fun, ao gbe sori Aso funfun nibiti oju elomiran koti ni le ri, tobadi ojo keta, ao gbe pamo sinu cupboard tabi apoti kan Lilo re :::::::::: Emeta lao ma lo ise yi larin ose kan lalaale Ojo akoko Monday mojumo Tuesday…. Ojo elekeji….Tuesday mojumo Wednesday Ojo eleketa…Friday mojumo Saturday pelu oti GIN.. AKIYESI PATAKI 1) Aso funfun lao ma fi bora, Aso funfun lao ma te sun, 2) ojo ti aba lo ogun yi ao gbodo sun ti eda alaye kan..eniyan kosi ni sun ti wa, 3) Enikeni kosi gbodo jiwa loju orun, ni ojo kijo ti aba ti lo nlo ogun yio, afi ki aji funrawa, tiwon ba jiwa oluware ma ku nio… Nitori ti aba ti lo ogun yi ti aba sun, Emi (spirit) yio ti jade kuro lara wa, yio ti ma lo si gbogbo ibiti gbogbo awon ojogbon aiye ti npe ni gbogbo agbaiye.. 4) O lewu pupo ki obinrin tun fi oju kan wa ni kete ti aba lo ogun yi tan o. 5) Ti abafe lo ogun yi, ao jinna si ibiti won ti le ma pariwo tabi diwa lowo ni o. 6) Ti aba fe lo ise yi ni ale, ao tan atupa oloju merindinlogun sile pelu awon eroja yi. Eyinju ekun mejeji toje ikanna, Eyinju aja mejeji toje ikanna,, Eyinju ologbo mejeji toje ikanna, Eyinju eta mejeji toje ikanna.. Ao jo won papo, ao rosinu ado ide, ao ma fi tan atupa oloju merindinlogun lojo ti abafe lo ogun yi, ao mu die ninu ebu yi mo tiro, ao lo osun die mo, ao le soju otun, ao tun lo efun die mo ekeji pelu tiro ao le soju osin. 7) Ao gbodo ma so gbogbo nkan ti oju wa ba nri sita o.. 8) Ao ma lo ogun yi ni ose ose bee fun osu merinla, leyin eyi ao ma lo be fun ose akoko ati ose igbeyin osu….. 9) Ti aba lo ogun yi lojo Monday…. Ori ile ni won
yoo gbewa lo se ipade, tobadi Tuesday ti aba lo inu sanmo ni won yio gbe wa lo se ipade, ti aba lo lojo jimoh inu omi niwon yio gbewa lo lati lo se ipade, ki amase foya rara ooo, 10) Ti aba pa ipade je… Won yio fun wa ni ijiya to too, ipade meteta se pataki gidigan, Sugbon ipade akoko niwon yio ti so gbogbo ofin ati Ilana ati irin na funwa Finni finni….. 11) Ti oba ri ise yi se, ikankan ninu awon eniyan re kotun ri inira ati ijiya mo ninu aiye yi, nitori oti di aabo le won lori.. 12) Saara ti ao ma se lossosu niyi…. Eran ewure ati pepeye ni ajo re ni osossu. 13)ti ao ba ti pe omo ogoji odun ao gbodo lo ise yi rara oo, 14) Obinrin kilo obinrin kiifoju ri, obinrin kiifoju kanwa nigbati aba lo… 15) Akii fi owo lasan bu ebu ogun yii o, Ekanna________ lao ma fi bu, deede eyiti oba ti bu yen na ni ao lo pelu oti hot lord tabi oti to ba lagbara. E se adupe.IMULE AARE AGBAYE (OSO IMULE NLA) A BE ENIKENI TI OJO ORI RE KO BA TO OGOJI ODUN KO MASE DAN OGUN YII WO RARA (40 YEARS) Eye Igun nla ooye kan, ao Jo pelu ataare nla kan nilu kan lojo aiku ao Di ao fi pamo soto Eye kan-nakan-na ooye kan, ao lo jo pelu ataare kan ni ilu Miran yatosi ilu tatijo takoko lojo aiku miran .ao di ao fi pamo soto Olongbo dudu ti koni awo miran lara tiba si ri daju wipe olongbo dudu ni eyo kan, ao Jo bakanna pelu ataare kan ilu miran lojo aiku miran ao di ao tun fi pamo soto. Oga ooye kan, ao Jo pelu ataare odidi kan nilu miran lojo aiku Ao wa ro gbogbo re papo sinu akeregbe, ao pa eran ewure kan fun, ao gbe sori Aso funfun nibiti oju elomiran koti ni le ri, tobadi ojo keta, ao gbe pamo sinu cupboard tabi apoti kan Lilo re :::::::::: Emeta lao ma lo ise yi larin ose kan lalaale
Ojo akoko Monday mojumo Tuesday…. Ojo elekeji….Tuesday mojumo Wednesday Ojo eleketa…Friday mojumo Saturday pelu oti GIN.. AKIYESI PATAKI 1) Aso funfun lao ma fi bora, Aso funfun lao ma te sun, 2) ojo ti aba lo ogun yi ao gbodo sun ti eda alaye kan..eniyan kosi ni sun ti wa, 3) Enikeni kosi gbodo jiwa loju orun, ni ojo kijo ti aba ti lo nlo ogun yio, afi ki aji funrawa, tiwon ba jiwa oluware ma ku nio… Nitori ti aba ti lo ogun yi ti aba sun, Emi (spirit) yio ti jade kuro lara wa, yio ti ma lo si gbogbo ibiti gbogbo awon ojogbon aiye ti npe ni gbogbo agbaiye.. 4) O lewu pupo ki obinrin tun fi oju kan wa ni kete ti aba lo ogun yi tan o. 5) Ti abafe lo ogun yi, ao jinna si ibiti won ti le ma pariwo tabi diwa lowo ni o. 6) Ti aba fe lo ise yi ni ale, ao tan atupa oloju merindinlogun sile pelu awon eroja yi. Eyinju ekun mejeji toje ikanna, Eyinju aja mejeji toje ikanna,, Eyinju ologbo mejeji toje ikanna, Eyinju eta mejeji toje ikanna.. Ao jo won papo, ao rosinu ado ide, ao ma fi tan atupa oloju merindinlogun lojo ti abafe lo ogun yi, ao mu die ninu ebu yi mo tiro, ao lo osun die mo, ao le soju otun, ao tun lo efun die mo ekeji pelu tiro ao le soju osin. 7) Ao gbodo ma so gbogbo nkan ti oju wa ba nri sita o.. 8) Ao ma lo ogun yi ni ose ose bee fun osu merinla, leyin eyi ao ma lo be fun ose akoko ati ose igbeyin osu….. 9) Ti aba lo ogun yi lojo Monday…. Ori ile ni won yoo gbewa lo se ipade, tobadi Tuesday ti aba lo inu sanmo ni won yio gbe wa lo se ipade, ti aba lo lojo jimoh inu omi niwon yio gbewa lo lati lo se ipade, ki amase foya rara ooo, 10) Ti aba pa ipade je… Won yio fun wa ni ijiya to too, ipade meteta se pataki gidigan,
Sugbon ipade akoko niwon yio ti so gbogbo ofin ati Ilana ati irin na funwa Finni finni….. 11) Ti oba ri ise yi se, ikankan ninu awon eniyan re kotun ri inira ati ijiya mo ninu aiye yi, nitori oti di aabo le won lori.. 12) Saara ti ao ma se lossosu niyi…. Eran ewure ati pepeye ni ajo re ni osossu. 13)ti ao ba ti pe omo ogoji odun ao gbodo lo ise yi rara oo, 14) Obinrin kilo obinrin kiifoju ri, obinrin kiifoju kanwa nigbati aba lo… 15) Akii fi owo lasan bu ebu ogun yii o, Ekanna________ lao ma fi bu, deede eyiti oba ti bu yen na ni ao lo pelu oti hot lord tabi oti to ba lagbara. : AMUNIYE… A o pa aguntan ibile kan, (kii se ti awon ahusa yen ooo), a o gba eje re sibi kan, a o wa yo apa osi re ni tutu tirun-tirun, a o gee si 16, eku asin 16, oga gbigbe 16, isu gbigbe a o gee si 16, ewe aluki, ewe ajeobale, eso ogirisako, Odidi atare 16, a o fi iyerosun te ifa osa meji sinu ape tuntun ti a fe fi jo oogun yii, a o ko apa aguntan yen tele, a o wa ko gbogbo awon nkan to ku lee lori, o di jijo papo, ti o ba jo tan, a o wa daa sinu eje aguntan yen, a o roo papo daadaa, a o wa saa ti yio gbe, a o wa tun-un lo kunna, a o roo sinu seere nla ti o le gbaa, a o maa te ni osa meji, a o maa pe ofo re sii, a o maa fi foko mu ni alaale…… *OFO-REE..* Amuniye 3*, Afoniye 3*, iya toboje 3*, iya tobosi 3*, iya mi osu ikun 3*, iya mi osu ide 3*, iya olominiminiye 3*, eyin mejeeje yii le tele orunmila lo si otu ife, igba ti e de ohun, won ni awon yio ka eewo fun yin, eni kini ohun eewo naa, won ni e o gbodo kala ejio, won ni e o gbodo te osun ailoro, won ni e o gbodo ro dede ni imosu, won ni e o gbodo fe iya oran laya, won ni e o gbodo fi omo wewe otu ife se ewa je, igba ti orunmila ka eewo fun yin tan, o gbe apo re, o kori sile sile ado, igba ti o lo tan, e kala ejio je, e te osun ailoran, e ro dede ni imosu, e de iya oran laya, e fi omo wewe otu ife se ewa je, ni won ba lo kesi orunmila wa, o ni ohun yio payin bo oke ponri re, eni enikeni ti o ba mo oruko eyin mejeeje yii, to si mon iyerosun ti won fi apa aguntan te, e ni eyin o nii di lowo mon, emi L omo L mo ti mon oruko eyin mejeeje yii loni, e ko idaamu kuro ninu aiye mi, e ko wahala kuro ninu aiye mi, airina, airilo, e koo kuro ninu aiye mi, (adura), toriwipe ikini yin amuniye, ikeji yin afoniye, ikeeta yin iyatoboje, ikeerin yin iyatobosi, ikaarun yin mesuku, ikeefa yin osu ide, ikeeje yin olominiminiye, iyerosun ti a fi apa osi aguntan te ohun ree ooo, e je ki aiye mi o ye mi ooo…
ثخيثم غيليا لASIRI TI ANABI SULEIMAN FIN PASE.
Ao Han oruko yi si ara gold ring ni ojo Sunday ama wa fi oruka na si owo otun, olohun ate gbogbo awon eyan ati emi airi fun eniti oba sise Yi
Atakpawi, Asolaty.